Iṣe Apo 10:20 YCE

20 Njẹ dide, sọkalẹ ki o si ba wọn lọ, máṣe kọminu ohunkohun: nitori emi li o rán wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 10

Wo Iṣe Apo 10:20 ni o tọ