Iṣe Apo 10:45 YCE

45 Ẹnu si yà awọn onigbagbọ ti ìkọlà, iye awọn ti o ba Peteru wá, nitoriti a tu ẹbùn Ẹmi Mimọ́ sori awọn Keferi pẹlu.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 10

Wo Iṣe Apo 10:45 ni o tọ