Iṣe Apo 10:7 YCE

7 Nigbati angẹli na ti o ba Korneliu sọ̀rọ si fi i silẹ lọ, o pè meji ninu awọn iranṣẹ ile rẹ̀, ati ọmọ-ogun olufọkànsin kan, ninu awọn ti ima duro tì i nigbagbogbo;

Ka pipe ipin Iṣe Apo 10

Wo Iṣe Apo 10:7 ni o tọ