Iṣe Apo 11:21 YCE

21 Ọwọ́ Oluwa si wà pẹlu wọn: ọpọlọpọ awọn ti o gbagbọ́ yipada si Oluwa.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 11

Wo Iṣe Apo 11:21 ni o tọ