Iṣe Apo 12:4 YCE

4 Nigbati o si mu u, o fi i sinu tubu, o fi i le ẹ̀ṣọ́ mẹrin awọn ọmọ-ogun lọwọ lati ma ṣọ ọ; o nrò lati mu u jade fun awọn enia wá lẹhin Irekọja.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 12

Wo Iṣe Apo 12:4 ni o tọ