Iṣe Apo 13:22 YCE

22 Nigbati o si mu u kuro, o gbé Dafidi dide li ọba fun wọn; ẹniti o si jẹri rẹ̀ pe, Mo ri Dafidi ọmọ Jesse ẹni bi ọkàn mi, ti yio ṣe gbogbo ifẹ mi.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 13

Wo Iṣe Apo 13:22 ni o tọ