Iṣe Apo 13:5 YCE

5 Nigbati nwọn si wà ni Salami, nwọn nwasu ọ̀rọ Ọlọrun ni sinagogu awọn Ju: nwọn si ni Johanu pẹlu fun iranṣẹ wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 13

Wo Iṣe Apo 13:5 ni o tọ