Iṣe Apo 13:50 YCE

50 Ṣugbọn awọn Ju rú awọn obinrin olufọkansin ati ọlọlá soke ati awọn àgba ilu na, nwọn si gbe inunibini dide si Paulu on Barnaba, nwọn si ṣí wọn kuro li àgbegbe wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 13

Wo Iṣe Apo 13:50 ni o tọ