Iṣe Apo 14:13 YCE

13 Alufa Jupiteri ti ile oriṣa rẹ̀ wà niwaju ilu wọn, si mu malu ati màriwo wá si ẹnubode, on iba si rubọ pẹlu awọn enia.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 14

Wo Iṣe Apo 14:13 ni o tọ