Iṣe Apo 14:23 YCE

23 Nigbati nwọn si ti yàn awọn àgbagba fun olukuluku ijọ, ti nwọn si ti fi àwẹ gbadura, nwọn fi wọn le Oluwa lọwọ, ẹniti nwọn gbagbọ́.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 14

Wo Iṣe Apo 14:23 ni o tọ