Iṣe Apo 14:27 YCE

27 Nigbati nwọn si de, ti nwọn si pè ijọ jọ, nwọn ròhin gbogbo ohun ti Ọlọrun fi wọn ṣe, ati bi o ti ṣí ilẹkun igbagbọ́ fun awọn Keferi.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 14

Wo Iṣe Apo 14:27 ni o tọ