Iṣe Apo 15:12 YCE

12 Gbogbo ajọ si dakẹ, nwọn si fi eti si Barnaba on Paulu, ti nwọn nròhin iṣẹ aṣẹ ati iṣẹ àmi ti Ọlọrun ti ti ọwọ́ wọn ṣe lãrin awọn Keferi.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 15

Wo Iṣe Apo 15:12 ni o tọ