Iṣe Apo 15:2 YCE

2 Nigbati iyapa ati iyàn jijà ti mbẹ lãrin Paulu on Barnaba kò si mọ ni ìwọn, awọn arakunrin yàn Paulu on Barnaba, ati awọn miran ninu wọn, ki nwọn goke lọ si Jerusalemu, sọdọ awọn aposteli ati awọn àgbagba nitori ọ̀ran yi.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 15

Wo Iṣe Apo 15:2 ni o tọ