Iṣe Apo 15:35 YCE

35 Paulu on Barnaba si duro diẹ ni Antioku, nwọn nkọ́ni, nwọn si nwasu ọ̀rọ Oluwa, ati awọn pipọ miran pẹlu wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 15

Wo Iṣe Apo 15:35 ni o tọ