Iṣe Apo 17:23 YCE

23 Nitori bi mo ti nkọja lọ, ti mo wò ohun wọnni ti ẹnyin nsìn, mo si ri pẹpẹ kan ti a kọ akọle yi si, FUN ỌLỌRUN AIMỌ̀. Njẹ ẹniti ẹnyin nsìn li aimọ̀ on na li emi nsọ fun nyin.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 17

Wo Iṣe Apo 17:23 ni o tọ