Iṣe Apo 17:30 YCE

30 Pẹlupẹlu igba aimọ̀ yi li Ọlọrun ti foju fò da; ṣugbọn nisisiyi o paṣẹ fun gbogbo enia nibi gbogbo lati ronupiwada:

Ka pipe ipin Iṣe Apo 17

Wo Iṣe Apo 17:30 ni o tọ