Iṣe Apo 17:6 YCE

6 Nigbati nwọn kò si ri wọn, nwọn wọ́ Jasoni, ati awọn arakunrin kan tọ̀ awọn olori ilu lọ, nwọn nkigbe pe, Awọn wọnyi ti o ti yi aiye po wá si ihinyi pẹlu;

Ka pipe ipin Iṣe Apo 17

Wo Iṣe Apo 17:6 ni o tọ