Iṣe Apo 18:19 YCE

19 O si sọkalẹ wá si Efesu, o si fi wọn silẹ nibẹ̀: ṣugbọn on tikararẹ̀ wọ̀ inu sinagogu lọ, o si ba awọn Ju fi ọrọ we ọrọ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 18

Wo Iṣe Apo 18:19 ni o tọ