Iṣe Apo 18:27 YCE

27 Nigbati o si nfẹ kọja lọ si Akaia, awọn arakunrin gba a ni iyanju, nwọn si kọwe si awọn ọmọ-ẹhin ki nwọn ki o gba a: nigbati o si de, o ràn awọn ti o gbagbọ́ nipa ore-ọfẹ lọwọ pupọ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 18

Wo Iṣe Apo 18:27 ni o tọ