Iṣe Apo 18:8 YCE

8 Ati Krispu, olori sinagogu, o gbà Oluwa gbọ́ pẹlu gbogbo ile rẹ̀; ati ọ̀pọ ninu awọn ara Korinti, nigbati nwọn gbọ́, nwọn gbagbọ́, a si baptisi wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 18

Wo Iṣe Apo 18:8 ni o tọ