Iṣe Apo 19:27 YCE

27 Ki si iṣe pe kìki iṣẹ-ọnà wa yi li o wà li ewu ati di asan; ṣugbọn ile Diana oriṣa nla yio si di gigàn pẹlu, ati gbogbo ọla nla rẹ̀ yio si run, ẹniti gbogbo Asia ati gbogbo aiye mbọ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 19

Wo Iṣe Apo 19:27 ni o tọ