Iṣe Apo 19:35 YCE

35 Nigbati akọwe ilu si mu ki ijọ enia dakẹ, o ni, Ẹnyin ará Efesu, tali ẹniti o wà ti kò mọ̀ pe, ilu ara Efesu ni iṣe olusin Diana oriṣa nla, ati ti ere ti o ti ọdọ Jupiteri bọ́ silẹ?

Ka pipe ipin Iṣe Apo 19

Wo Iṣe Apo 19:35 ni o tọ