Iṣe Apo 2:7 YCE

7 Hà si ṣe gbogbo wọn, ẹnu si yà wọn, nwọn nwi fun ara wọn pe, Wo o, ara Galili ki gbogbo awọn ti nsọ̀rọ wọnyi iṣe?

Ka pipe ipin Iṣe Apo 2

Wo Iṣe Apo 2:7 ni o tọ