Iṣe Apo 20:1 YCE

1 NIGBATI ariwo na si rọlẹ, Paulu ranṣẹ pè awọn ọmọ-ẹhin, o si gbà wọn ni iyanju, o dagbere fun wọn, o dide lati lọ si Makedonia.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 20

Wo Iṣe Apo 20:1 ni o tọ