Iṣe Apo 20:18 YCE

18 Nigbati nwọn si de ọdọ rẹ̀, o wi fun wọn pe, Ẹnyin tikaranyin mọ̀, lati ọjọ ikini ti mo ti de Asia, bi emi ti ba nyin gbé, ni gbogbo akoko na,

Ka pipe ipin Iṣe Apo 20

Wo Iṣe Apo 20:18 ni o tọ