Iṣe Apo 20:30 YCE

30 Ati larin ẹnyin tikaranyin li awọn enia yio dide, ti nwọn o ma sọ̀rọ òdi, lati fà awọn ọmọ-ẹhin sẹhin wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 20

Wo Iṣe Apo 20:30 ni o tọ