Iṣe Apo 20:32 YCE

32 Njẹ nisisiyi, ará, mo fi nyin le Ọlọrun lọwọ ati ọ̀rọ ore-ọfẹ rẹ̀, ti o le gbe nyin duro, ti o si le fun nyin ni ini lãrin gbogbo awọn ti a sọ di mimọ́.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 20

Wo Iṣe Apo 20:32 ni o tọ