Iṣe Apo 22:30 YCE

30 Ni ijọ keji, nitoriti o fẹ mọ̀ dajudaju ohun ti awọn Ju nfi i sùn si, o tú u silẹ, o paṣẹ ki awọn olori alufa ati gbogbo igbimọ pejọ, o si mu Paulu sọkalẹ, o si mu u duro niwaju wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 22

Wo Iṣe Apo 22:30 ni o tọ