Iṣe Apo 22:9 YCE

9 Awọn ti o si wà pẹlu mi ri imọlẹ na nitõtọ, ẹ̀ru si ba wọn; ṣugbọn nwọn kò gbọ́ ohùn ẹniti mba mi sọrọ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 22

Wo Iṣe Apo 22:9 ni o tọ