Iṣe Apo 25:16 YCE

16 Awọn ẹniti mo si da lohùn pe, Kì iṣe iṣe awọn ara Romu lati da ẹnikẹni lẹbi, ki ẹniti a fisùn ki o to kò awọn olufisùn rẹ̀ loju, ki o si ri àye wi ti ẹnu rẹ̀, nitori ọ̀ran ti a kà si i lọrùn,

Ka pipe ipin Iṣe Apo 25

Wo Iṣe Apo 25:16 ni o tọ