Iṣe Apo 26:26 YCE

26 Nitori ọba mọ̀ nkan gbogbo wọnyi, niwaju ẹniti emi nsọ̀rọ li aibẹ̀ru: nitori mo gbagbọ pe ọkan ninu nkan wọnyi kò pamọ fun u, nitoriti a kò ṣe nkan yi ni ìkọkọ.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 26

Wo Iṣe Apo 26:26 ni o tọ