Iṣe Apo 27:10 YCE

10 O si wi fun wọn pe, Alàgba, mo woye pe iṣikọ̀ yi yio li ewu ati òfo pipọ, kì iṣe kìki ti ẹrù ati ti ọkọ̀, ṣugbọn ti ẹmí wa pẹlu.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 27

Wo Iṣe Apo 27:10 ni o tọ