Iṣe Apo 27:41 YCE

41 Nigbati nwọn si de ibiti okun meji pade, nwọn fi ori ọkọ̀ sọlẹ; iwaju rẹ̀ si kàn mọlẹ ṣinṣin, o duro, kò le yi, ṣugbọn agbara riru omi bẹrẹ si fọ́ idi ọkọ̀ na.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 27

Wo Iṣe Apo 27:41 ni o tọ