Iṣe Apo 27:7 YCE

7 Nigbati awa nlọ jẹ́jẹ li ọjọ pipọ, ti awa fi agbara kaka de ọkankan Knidu, ti afẹfẹ kò bùn wa làye, awa lọ lẹba Krete, li ọkankan Salmone;

Ka pipe ipin Iṣe Apo 27

Wo Iṣe Apo 27:7 ni o tọ