Iṣe Apo 28:14 YCE

14 Nibiti a gbé ri awọn arakunrin, ti nwọn si bẹ̀ wa lati ba wọn gbé ni ijọ meje: bẹ̃li awa si lọ si ìha Romu.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 28

Wo Iṣe Apo 28:14 ni o tọ