Iṣe Apo 28:25 YCE

25 Nigbati ohùn wọn kò ṣọ̀kan lãrin ara wọn, nwọn tuká, lẹhin igbati Paulu sọ̀rọ kan pe, Otitọ li Ẹmí Mimọ́ sọ lati ẹnu woli Isaiah wá fun awọn baba wa,

Ka pipe ipin Iṣe Apo 28

Wo Iṣe Apo 28:25 ni o tọ