Iṣe Apo 3:11 YCE

11 Bi arọ ti a mu larada si ti di Peteru on Johanu mu, gbogbo enia jumọ sure jọ tọ̀ wọn lọ ni iloro ti a npè ni ti Solomoni, ẹnu yà wọn gidigidi.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 3

Wo Iṣe Apo 3:11 ni o tọ