19 Nitorina ẹ ronupiwada, ki ẹ si tun yipada, ki a le pa ẹ̀ṣẹ nyin rẹ́, ki akoko itura ba le ti iwaju Oluwa wá,
Ka pipe ipin Iṣe Apo 3
Wo Iṣe Apo 3:19 ni o tọ