25 Ẹnyin li ọmọ awọn woli, ati ti majẹmu tí Ọlọrun ti ba awọn baba nyin dá nigbati o wi fun Abrahamu pe, Ati ninu irú-ọmọ rẹ li a ti fi ibukun fun gbogbo idile aiye.
Ka pipe ipin Iṣe Apo 3
Wo Iṣe Apo 3:25 ni o tọ