Iṣe Apo 4:19 YCE

19 Ṣugbọn Peteru on Johanu dahùn, nwọn si wi fun wọn pe, Bi o ba tọ́ li oju Ọlọrun lati gbọ́ ti nyin jù ti Ọlọrun lọ, ẹ gbà a rò,

Ka pipe ipin Iṣe Apo 4

Wo Iṣe Apo 4:19 ni o tọ