Iṣe Apo 4:21 YCE

21 Nigbati nwọn si kìlọ fun wọn si i, nwọn jọwọ wọn lọwọ lọ, nigbati nwọn kò ti ri nkan ti nwọn iba fi jẹ wọn ni ìya, nitori awọn enia: nitori gbogbo wọn ni nyìn Ọlọrun logo fun ohun ti a ṣe.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 4

Wo Iṣe Apo 4:21 ni o tọ