Iṣe Apo 4:23 YCE

23 Nigbati nwọn si jọwọ wọn lọwọ lọ, nwọn lọ sọdọ awọn ẹgbẹ wọn, nwọn si ròhin ohun gbogbo ti awọn olori alufa ati awọn agbàgba sọ fun wọn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 4

Wo Iṣe Apo 4:23 ni o tọ