Iṣe Apo 5:36 YCE

36 Nitori ṣaju ọjọ wọnyi ni Teuda dide, o nwipe ẹni nla kan li on; ẹniti ìwọn irinwo ọkunrin gbatì: ẹniti a pa; ati gbogbo iye awọn ti o gbà tirẹ̀, a tú wọn ká, a si sọ wọn di asan.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 5

Wo Iṣe Apo 5:36 ni o tọ