Iṣe Apo 6:9 YCE

9 Ṣugbọn awọn kan dide ninu awọn ti sinagogu, ti a npè ni ti awọn Libertine, ati ti ara Kirene, ati ti ara Aleksandria, ati ninu awọn ara Kilikia, ati ti Asia nwọn mba Stefanu jiyàn.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 6

Wo Iṣe Apo 6:9 ni o tọ