10 O si yọ ọ kuro ninu ipọnju rẹ̀ gbogbo, o si fun u li ojurere ati ọgbọ́n li oju Farao ọba Egipti; on si fi i jẹ bãlẹ Egipti ati gbogbo ile rẹ̀.
Ka pipe ipin Iṣe Apo 7
Wo Iṣe Apo 7:10 ni o tọ