Iṣe Apo 7:23 YCE

23 Nigbati o si di ẹni iwọn ogoji ọdún, o sọ si i lọkan lati lọ ibẹ̀ awọn ọmọ Israeli ará rẹ̀ wò.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 7

Wo Iṣe Apo 7:23 ni o tọ