34 Ni riri mo ti ri ipọnju awọn enia mi ti mbẹ ni Egipti, mo si ti gbọ́ gbigbin wọn, mo si sọkalẹ wá lati gbà wọn. Wá nisisiyi, emi o si rán ọ lọ si Egipti.
Ka pipe ipin Iṣe Apo 7
Wo Iṣe Apo 7:34 ni o tọ