Iṣe Apo 7:38 YCE

38 Eyi na li ẹniti o wà ninu ijọ ni ijù pẹlu angẹli na ti o ba a sọ̀rọ li òke Sinai, ati pẹlu awọn baba wa: ẹniti o gbà ọ̀rọ ìye lati fifun wa:

Ka pipe ipin Iṣe Apo 7

Wo Iṣe Apo 7:38 ni o tọ