Iṣe Apo 8:1 YCE

1 SAULU si li ohùn si ikú rẹ̀. Li akoko na, inunibini nla kan dide si ijọ ti o wà ni Jerusalemu; a si tú gbogbo wọn kalẹ já àgbegbe Judea on Samaria, afi awọn aposteli.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 8

Wo Iṣe Apo 8:1 ni o tọ