Iṣe Apo 8:12 YCE

12 Ṣugbọn nigbati nwọn gbà Filippi gbọ́ ẹniti nwasu ihinrere ti ijọba Ọlọrun, ati orukọ Jesu Kristi, a baptisi wọn, ati ọkunrin ati obinrin.

Ka pipe ipin Iṣe Apo 8

Wo Iṣe Apo 8:12 ni o tọ